Ìfihàn 17:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n máa bá Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà jà,+ àmọ́, torí òun ni Olúwa àwọn olúwa àti Ọba àwọn ọba,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà máa ṣẹ́gun wọn.+ Bákan náà, àwọn tí a pè tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀, tí wọ́n jẹ́ àyànfẹ́ àti olóòótọ́ máa ṣẹ́gun pẹ̀lú.”+ Ìfihàn 19:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Mo sì rí i tí ẹranko náà àti àwọn ọba ayé pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun wọn kóra jọ láti bá ẹni tó jókòó sórí ẹṣin àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jagun.+
14 Wọ́n máa bá Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà jà,+ àmọ́, torí òun ni Olúwa àwọn olúwa àti Ọba àwọn ọba,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà máa ṣẹ́gun wọn.+ Bákan náà, àwọn tí a pè tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀, tí wọ́n jẹ́ àyànfẹ́ àti olóòótọ́ máa ṣẹ́gun pẹ̀lú.”+
19 Mo sì rí i tí ẹranko náà àti àwọn ọba ayé pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun wọn kóra jọ láti bá ẹni tó jókòó sórí ẹṣin àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jagun.+