Hébérù 7:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Torí irú àlùfáà àgbà yìí ló yẹ wá, ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin, aláìṣẹ̀, aláìlẹ́gbin,+ ẹni tí a yà sọ́tọ̀ láàárín àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbé ga ju ọ̀run lọ.+
26 Torí irú àlùfáà àgbà yìí ló yẹ wá, ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin, aláìṣẹ̀, aláìlẹ́gbin,+ ẹni tí a yà sọ́tọ̀ láàárín àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbé ga ju ọ̀run lọ.+