Àìsáyà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ojú èèyàn tó ń gbéra ga máa wálẹ̀,A sì máa tẹrí ìgbéraga àwọn èèyàn ba.* Jèhófà nìkan la máa gbé ga ní ọjọ́ yẹn.
11 Ojú èèyàn tó ń gbéra ga máa wálẹ̀,A sì máa tẹrí ìgbéraga àwọn èèyàn ba.* Jèhófà nìkan la máa gbé ga ní ọjọ́ yẹn.