Àìsáyà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jèhófà, ìwọ ni Ọlọ́run mi. Mo gbé ọ ga, mo yin orúkọ rẹ,Torí o ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+Àwọn ohun tí o pinnu* láti ìgbà àtijọ́,+Nínú òtítọ́,+ nínú ìfọkàntán. Hébérù 13:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+ Ìfihàn 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ Jèhófà,* tí kò ní yin orúkọ rẹ lógo, torí pé ìwọ nìkan ni adúróṣinṣin?+ Torí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè máa wá jọ́sìn níwájú rẹ,+ torí a ti fi àwọn àṣẹ òdodo rẹ hàn kedere.”
25 Jèhófà, ìwọ ni Ọlọ́run mi. Mo gbé ọ ga, mo yin orúkọ rẹ,Torí o ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+Àwọn ohun tí o pinnu* láti ìgbà àtijọ́,+Nínú òtítọ́,+ nínú ìfọkàntán.
15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+
4 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ Jèhófà,* tí kò ní yin orúkọ rẹ lógo, torí pé ìwọ nìkan ni adúróṣinṣin?+ Torí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè máa wá jọ́sìn níwájú rẹ,+ torí a ti fi àwọn àṣẹ òdodo rẹ hàn kedere.”