Òwe 14:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn tó sún mọ́ tálákà pàápàá máa ń kórìíra rẹ̀,+Àmọ́ ọ̀pọ̀ èèyàn ló ń bá olówó ṣọ̀rẹ́.+