- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 29:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 “Síbẹ̀, ta ni mí, ta sì ni àwọn èèyàn mi, tí a fi máa láǹfààní láti ṣe ọrẹ àtinúwá bí irú èyí? Nítorí ọ̀dọ̀ rẹ ni ohun gbogbo ti wá, ohun tó ti ọwọ́ rẹ wá ni a sì fi fún ọ. 
 
-