ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 22:21-23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  21 Gbà mí kúrò lẹ́nu kìnnìún  + àti lọ́wọ́ ìwo akọ màlúù igbó;

      Dá mi lóhùn, kí o sì gbà mí sílẹ̀.

      22 Màá sọ orúkọ rẹ fún àwọn arákùnrin mi;+

      Màá sì yìn ọ́ láàárín ìjọ.+

      23 Ẹ̀yin tí ẹ bẹ̀rù Jèhófà, ẹ yìn ín!

      Gbogbo ẹ̀yin ọmọ* Jékọ́bù, ẹ yìn ín lógo!+

      Ẹ máa bẹ̀rù rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ọmọ* Ísírẹ́lì.

  • Sáàmù 50:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ẹni tó mú ọpẹ́ wá, tí ó fi rúbọ sí mi ń yìn mí lógo,+

      Ní ti ẹni tó sì ń rin ọ̀nà tí ó tọ́,

      Màá mú kí ó rí ìgbàlà látọ̀dọ̀ mi.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́