- 
	                        
            
            Jeremáyà 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Kálukú ń rẹ́ ọmọnìkejì rẹ̀ jẹ, Kò sì sí ẹni tó ń sọ òtítọ́. Wọ́n ti kọ́ ahọ́n wọn láti máa pa irọ́.+ Wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ títí ó fi rẹ̀ wọ́n. 
 
-