Sáàmù 32:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà) Sáàmù 40:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn àjálù tó yí mi ká kò ṣeé kà.+ Àwọn àṣìṣe mi pọ̀ débi pé mi ò tiẹ̀ mọ ibi tí mo forí lé;+Wọ́n pọ̀ ju irun orí mi lọ,Ìrẹ̀wẹ̀sì sì ti bá ọkàn mi.
5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà)
12 Àwọn àjálù tó yí mi ká kò ṣeé kà.+ Àwọn àṣìṣe mi pọ̀ débi pé mi ò tiẹ̀ mọ ibi tí mo forí lé;+Wọ́n pọ̀ ju irun orí mi lọ,Ìrẹ̀wẹ̀sì sì ti bá ọkàn mi.