ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 13:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Mánóà wá sọ fún ìyàwó rẹ̀ pé: “Ó dájú pé a máa kú, torí Ọlọ́run ni a rí.”+ 23 Àmọ́ ìyàwó rẹ̀ sọ fún un pé: “Tó bá jẹ́ pé Jèhófà fẹ́ pa wá ni, kò ní gba ẹbọ sísun+ àti ọrẹ ọkà lọ́wọ́ wa, kò ní fi gbogbo nǹkan yìí hàn wá, kò sì ní sọ ìkankan nínú nǹkan wọ̀nyí fún wa.”

  • 1 Sámúẹ́lì 25:30, 31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Tí Jèhófà bá ti ṣe gbogbo ohun rere tí ó ṣèlérí fún olúwa mi, tí ó sì fi ọ́ ṣe olórí Ísírẹ́lì,+ 31 o ò ní banú jẹ́ tàbí kí o kábàámọ̀* nínú ọkàn rẹ pé o ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ láìnídìí tàbí pé olúwa mi fi ọwọ́ ara rẹ̀ gbẹ̀san.*+ Nígbà tí Jèhófà bá bù kún olúwa mi, kí o rántí ìránṣẹ́bìnrin rẹ.”

  • Ẹ́sítà 5:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Tí mo bá rí ojú rere ọba, tó bá sì wu ọba láti ṣe ohun tí mo fẹ́, kó sì fún mi ní ohun tí mo béèrè, kí ọba àti Hámánì wá síbi àsè tí màá sè fún wọn lọ́la; ọ̀la ni màá sì béèrè ohun tí ọba ní kí n béèrè.”

  • Títù 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Bákan náà, kí àwọn àgbà obìnrin jẹ́ ẹni tó ń bọ̀wọ̀ fúnni, kí wọ́n má ṣe jẹ́ abanijẹ́, kí wọ́n má ṣe jẹ́ ọ̀mùtí, kí wọ́n máa kọ́ni ní ohun rere,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́