Róòmù 16:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Mo fẹ́ kí ẹ mọ* Fébè arábìnrin wa, tó jẹ́ òjíṣẹ́ ní ìjọ tó wà ní Kẹnkíríà,+ 2 kí ẹ lè tẹ́wọ́ gbà á nínú Olúwa lọ́nà tó yẹ àwọn ẹni mímọ́, kí ẹ sì ràn án lọ́wọ́ nínú ohun tó bá nílò,+ torí òun fúnra rẹ̀ ti gbèjà ọ̀pọ̀ èèyàn, títí kan èmi náà.
16 Mo fẹ́ kí ẹ mọ* Fébè arábìnrin wa, tó jẹ́ òjíṣẹ́ ní ìjọ tó wà ní Kẹnkíríà,+ 2 kí ẹ lè tẹ́wọ́ gbà á nínú Olúwa lọ́nà tó yẹ àwọn ẹni mímọ́, kí ẹ sì ràn án lọ́wọ́ nínú ohun tó bá nílò,+ torí òun fúnra rẹ̀ ti gbèjà ọ̀pọ̀ èèyàn, títí kan èmi náà.