-
Ẹ́sítà 6:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Torí náà, Hámánì mú ẹ̀wù oyè àti ẹṣin náà, ó wọ aṣọ náà fún Módékáì,+ ó sì mú un gun ẹṣin ní gbàgede ìlú, ó ń kéde níwájú rẹ̀ pé: “Ohun tí wọ́n máa ń ṣe nìyí fún ẹni tó wu ọba pé kó dá lọ́lá!” 12 Lẹ́yìn náà, Módékáì pa dà sí ẹnubodè ọba, àmọ́ Hámánì yára lọ sí ilé rẹ̀, ó ń ṣọ̀fọ̀, ó sì bo orí rẹ̀.
-