Sáàmù 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Aláyọ̀ ni ẹni tí kì í tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn èèyàn burúkúTí kì í dúró ní ọ̀nà àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀+Tí kì í sì í jókòó lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹ́gàn.+ 1 Kọ́ríńtì 15:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ. Ẹgbẹ́ búburú ń ba ìwà rere* jẹ́.+
1 Aláyọ̀ ni ẹni tí kì í tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn èèyàn burúkúTí kì í dúró ní ọ̀nà àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀+Tí kì í sì í jókòó lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹ́gàn.+