Sáàmù 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí,*+Òfin rẹ sì wà nínú mi lọ́hùn-ún.+ Òwe 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọmọ mi, tí o bá gba àwọn ọ̀rọ̀ miTí o sì fi àwọn àṣẹ mi ṣe ìṣúra rẹ,+