1 Tímótì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí àǹfààní díẹ̀ wà nínú eré ìmárale,* àmọ́ ìfọkànsin Ọlọ́run ṣàǹfààní fún ohun gbogbo, ní ti pé ó ní ìlérí ìwàláàyè ní báyìí àti ìlérí ìwàláàyè ti ọjọ́ iwájú.+
8 Torí àǹfààní díẹ̀ wà nínú eré ìmárale,* àmọ́ ìfọkànsin Ọlọ́run ṣàǹfààní fún ohun gbogbo, ní ti pé ó ní ìlérí ìwàláàyè ní báyìí àti ìlérí ìwàláàyè ti ọjọ́ iwájú.+