-
Máàkù 7:21-23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Torí láti inú, láti ọkàn àwọn èèyàn,+ ni àwọn èrò burúkú ti ń wá: ìṣekúṣe,* olè jíjà, ìpànìyàn, 22 àwọn ìwà àgbèrè, ojúkòkòrò, àwọn ìwà burúkú, ẹ̀tàn, ìwà àìnítìjú,* ojú tó ń ṣe ìlara, ọ̀rọ̀ òdì, ìgbéraga àti ìwà òmùgọ̀. 23 Láti inú ni gbogbo nǹkan burúkú yìí ti ń wá, tí wọ́n sì ń sọ èèyàn di aláìmọ́.”
-