Mátíù 6:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Ojú ni fìtílà ara.+ Tí ojú rẹ bá mú ọ̀nà kan,* gbogbo ara rẹ máa mọ́lẹ̀ yòò.*