Òwe 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹnu òmùgọ̀ ni ìparun rẹ̀,+Ètè rẹ̀ sì jẹ́ ìdẹkùn fún ẹ̀mí* rẹ̀.