Jẹ́nẹ́sísì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+ Jẹ́nẹ́sísì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+ Nọ́ńbà 35:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹ ò gbọ́dọ̀ gba ìràpadà fún ẹ̀mí* apààyàn tí ikú tọ́ sí, ṣe ni kí ẹ pa á.+ Diutarónómì 27:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+
10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+
25 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)