Òwe 3:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọmọ mi, máa fi wọ́n* sọ́kàn. Má ṣe jẹ́ kí ọgbọ́n tó gbéṣẹ́ àti làákàyè bọ́ mọ́ ọ lọ́wọ́;22 Wọ́n á fún ọ* ní ìyèWọ́n á sì jẹ́ ọ̀ṣọ́ fún ọrùn rẹ;
21 Ọmọ mi, máa fi wọ́n* sọ́kàn. Má ṣe jẹ́ kí ọgbọ́n tó gbéṣẹ́ àti làákàyè bọ́ mọ́ ọ lọ́wọ́;22 Wọ́n á fún ọ* ní ìyèWọ́n á sì jẹ́ ọ̀ṣọ́ fún ọrùn rẹ;