Ẹ́kísódù 23:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “O ò gbọ́dọ̀ tan ìròyìn èké kálẹ̀.*+ Má ṣe lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú ẹni burúkú láti jẹ́rìí èké.+