Jẹ́nẹ́sísì 39:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Gbàrà tí ọ̀gá rẹ̀ gbọ́ ohun tí ìyàwó rẹ̀ sọ fún un pé: “Ohun tí ìránṣẹ́ rẹ ṣe sí mi nìyí,” inú bí i gan-an. 20 Ni ọ̀gá Jósẹ́fù bá ju Jósẹ́fù sí ẹ̀wọ̀n, níbi tí wọ́n ń kó àwọn ẹlẹ́wọ̀n ọba sí, ó sì wà níbẹ̀ nínú ẹ̀wọ̀n.+
19 Gbàrà tí ọ̀gá rẹ̀ gbọ́ ohun tí ìyàwó rẹ̀ sọ fún un pé: “Ohun tí ìránṣẹ́ rẹ ṣe sí mi nìyí,” inú bí i gan-an. 20 Ni ọ̀gá Jósẹ́fù bá ju Jósẹ́fù sí ẹ̀wọ̀n, níbi tí wọ́n ń kó àwọn ẹlẹ́wọ̀n ọba sí, ó sì wà níbẹ̀ nínú ẹ̀wọ̀n.+