Léfítíkù 19:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “‘Tí ẹ bá rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà lọ́nà tí ẹ ó fi rí ìtẹ́wọ́gbà.+