Òwe 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí ètè obìnrin oníwàkiwà* ń kán tótó bí afárá oyin,+Ọ̀rọ̀* rẹ̀ sì tuni lára ju òróró lọ.+