Òwe 15:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ẹni tó ń jẹ èrè tí kò tọ́ ń fa wàhálà* bá agbo ilé rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó kórìíra àbẹ̀tẹ́lẹ̀ yóò máa wà láàyè.+
27 Ẹni tó ń jẹ èrè tí kò tọ́ ń fa wàhálà* bá agbo ilé rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó kórìíra àbẹ̀tẹ́lẹ̀ yóò máa wà láàyè.+