Róòmù 16:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ọlọ́run, ẹnì kan ṣoṣo tí ó gbọ́n,+ ni kí ògo nípasẹ̀ Jésù Kristi jẹ́ tirẹ̀ títí láé. Àmín. 1 Kọ́ríńtì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ibo ni ọlọ́gbọ́n wà? Ibo ni akọ̀wé òfin* wà? Ibo ni òjiyàn ọ̀rọ̀ ètò àwọn nǹkan yìí* wà? Ṣé Ọlọ́run kò ti sọ ọgbọ́n ayé di òmùgọ̀ ni? Jémíìsì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́, ọgbọ́n tó wá láti òkè á kọ́kọ́ jẹ́ mímọ́,+ lẹ́yìn náà, ó lẹ́mìí àlàáfíà,+ ó ń fòye báni lò,+ ó ṣe tán láti ṣègbọràn, ó máa ń ṣàánú gan-an, ó sì ń so èso rere,+ kì í ṣe ojúsàájú,+ kì í sì í ṣe àgàbàgebè.+
20 Ibo ni ọlọ́gbọ́n wà? Ibo ni akọ̀wé òfin* wà? Ibo ni òjiyàn ọ̀rọ̀ ètò àwọn nǹkan yìí* wà? Ṣé Ọlọ́run kò ti sọ ọgbọ́n ayé di òmùgọ̀ ni?
17 Àmọ́, ọgbọ́n tó wá láti òkè á kọ́kọ́ jẹ́ mímọ́,+ lẹ́yìn náà, ó lẹ́mìí àlàáfíà,+ ó ń fòye báni lò,+ ó ṣe tán láti ṣègbọràn, ó máa ń ṣàánú gan-an, ó sì ń so èso rere,+ kì í ṣe ojúsàájú,+ kì í sì í ṣe àgàbàgebè.+