Sáàmù 33:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọ̀rọ̀ ni Jèhófà fi dá àwọn ọ̀run,+Nípa èémí* ẹnu rẹ̀ sì ni gbogbo ohun tó wà nínú wọn* fi wà. Jeremáyà 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Òun ni Aṣẹ̀dá ayé tó fi agbára rẹ̀ dá a,Ẹni tó fi ọgbọ́n rẹ̀ dá ilẹ̀ tó ń mú èso jáde+Tó sì fi òye rẹ̀ na ọ̀run bí aṣọ.+
12 Òun ni Aṣẹ̀dá ayé tó fi agbára rẹ̀ dá a,Ẹni tó fi ọgbọ́n rẹ̀ dá ilẹ̀ tó ń mú èso jáde+Tó sì fi òye rẹ̀ na ọ̀run bí aṣọ.+