Sáàmù 119:130 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 130 Ṣíṣí ọ̀rọ̀ rẹ payá ń mú ìmọ́lẹ̀ wá,+Ó ń fún àwọn aláìmọ̀kan ní òye.+