Òwe 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní ọgbọ́n, ní òye.+ Má gbàgbé, má sì kúrò nínú ohun tí mo sọ. Òwe 13:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹni tó ń bá ọlọ́gbọ́n rìn yóò gbọ́n,+Àmọ́ ẹni tó ń bá òmùgọ̀ da nǹkan pọ̀ yóò rí láburú.+