Òwe 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹlẹ́gàn kì í fẹ́ràn ẹni tó ń tọ́ ọ sọ́nà.*+ Kì í fi ọ̀rọ̀ lọ àwọn ọlọ́gbọ́n.+