Òwe 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọrọ̀* kò ní ṣeni láǹfààní ní ọjọ́ ìbínú ńlá,+Àmọ́ òdodo ló ń gbani lọ́wọ́ ikú.+