Sáàmù 33:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wò ó! Ojú Jèhófà ń ṣọ́ àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+Àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,19 Láti gbà wọ́n* sílẹ̀ lọ́wọ́ ikú,Kí ó sì mú kí wọ́n máa wà láàyè ní àkókò ìyàn.+ Sáàmù 37:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+ Mátíù 6:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+
18 Wò ó! Ojú Jèhófà ń ṣọ́ àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+Àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,19 Láti gbà wọ́n* sílẹ̀ lọ́wọ́ ikú,Kí ó sì mú kí wọ́n máa wà láàyè ní àkókò ìyàn.+
25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+
33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+