Sáàmù 112:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mìmì kan ò ní mì í láé.+ ל [Lámédì] A ó máa rántí àwọn olódodo títí láé.+ Oníwàásù 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Orúkọ rere* sàn ju òróró dáradára,+ ọjọ́ ikú sì sàn ju ọjọ́ tí a bíni lọ.