Òwe 5:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí o sì sọ pé: “Ẹ wo bí mo ṣe kórìíra ẹ̀kọ́ tó! Ẹ wo bí ọkàn mi ti ṣàìka ìbáwí sí! 13 Mi ò fetí sí ohùn àwọn tó ń kọ́ miMi ò sì tẹ́tí sí àwọn olùkọ́ mi. Jòhánù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń hùwà burúkú kórìíra ìmọ́lẹ̀, kì í sì í wá sínú ìmọ́lẹ̀, kí a má bàa dá àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́bi.*
12 Tí o sì sọ pé: “Ẹ wo bí mo ṣe kórìíra ẹ̀kọ́ tó! Ẹ wo bí ọkàn mi ti ṣàìka ìbáwí sí! 13 Mi ò fetí sí ohùn àwọn tó ń kọ́ miMi ò sì tẹ́tí sí àwọn olùkọ́ mi.
20 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń hùwà burúkú kórìíra ìmọ́lẹ̀, kì í sì í wá sínú ìmọ́lẹ̀, kí a má bàa dá àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́bi.*