-
Mátíù 12:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Ẹni rere máa ń mú ohun rere jáde látinú ìṣúra rere rẹ̀, àmọ́ ẹni burúkú máa ń mú ohun burúkú jáde látinú ìṣúra burúkú rẹ̀.+
-
-
Jémíìsì 3:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Bẹ́ẹ̀ náà ni ahọ́n jẹ́ ẹ̀yà ara tó kéré, síbẹ̀ ó máa ń fọ́nnu gan-an. Ẹ wo bí iná tí kò tó nǹkan ṣe lè jó igbó kìjikìji run!
-