Òwe 17:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹni tó bá ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini* ń wá ìfẹ́,+Àmọ́ ẹni tó bá ń tẹnu mọ́ ọ̀rọ̀ ṣáá ń tú ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ká.+ 1 Kọ́ríńtì 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìfẹ́+ máa ń ní sùúrù*+ àti inú rere.+ Ìfẹ́ kì í jowú,+ kì í fọ́nnu, kì í gbéra ga,+ 1 Kọ́ríńtì 13:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó máa ń mú ohun gbogbo mọ́ra,+ ó máa ń gba ohun gbogbo gbọ́,+ ó máa ń retí ohun gbogbo,+ ó máa ń fara da ohun gbogbo.+ 1 Pétérù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ara yín,+ torí ìfẹ́ máa ń bo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ mọ́lẹ̀.+
9 Ẹni tó bá ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini* ń wá ìfẹ́,+Àmọ́ ẹni tó bá ń tẹnu mọ́ ọ̀rọ̀ ṣáá ń tú ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ká.+
7 Ó máa ń mú ohun gbogbo mọ́ra,+ ó máa ń gba ohun gbogbo gbọ́,+ ó máa ń retí ohun gbogbo,+ ó máa ń fara da ohun gbogbo.+