Òwe 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹni tó ń ṣọ́ ẹnu rẹ̀* ń dáàbò bo ẹ̀mí* rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó ń la ẹnu rẹ̀ gbàgà yóò pa run.+ Òwe 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹnu òmùgọ̀ ni ìparun rẹ̀,+Ètè rẹ̀ sì jẹ́ ìdẹkùn fún ẹ̀mí* rẹ̀.