Sáàmù 37:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jẹ́ kí inú rẹ máa dùn jọjọ* nínú Jèhófà,Yóò sì fún ọ ní àwọn ohun tí ọkàn rẹ fẹ́. 1 Jòhánù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ohun tó dá wa lójú nípa rẹ̀ ni pé,*+ tí a bá béèrè ohunkóhun tó bá ìfẹ́ rẹ̀ mu, ó ń gbọ́ wa.+