Sáàmù 91:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Yóò ké pè mí, màá sì dá a lóhùn.+ Màá dúró tì í nígbà wàhálà.+ Màá gbà á sílẹ̀, màá sì ṣe é lógo. 16 Màá fi ẹ̀mí gígùn tẹ́ ẹ lọ́rùn,+Màá sì jẹ́ kó rí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà mi.”*+
15 Yóò ké pè mí, màá sì dá a lóhùn.+ Màá dúró tì í nígbà wàhálà.+ Màá gbà á sílẹ̀, màá sì ṣe é lógo. 16 Màá fi ẹ̀mí gígùn tẹ́ ẹ lọ́rùn,+Màá sì jẹ́ kó rí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà mi.”*+