Jóòbù 27:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Èyí ni ìpín èèyàn burúkú látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+Ogún tí àwọn oníwà ìkà gbà látọ̀dọ̀ Olódùmarè. 14 Tí àwọn ọmọ rẹ̀ bá pọ̀, wọ́n á fi idà pa wọ́n,+Àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ̀ ò sì ní ní oúnjẹ tó máa tó wọn.
13 Èyí ni ìpín èèyàn burúkú látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+Ogún tí àwọn oníwà ìkà gbà látọ̀dọ̀ Olódùmarè. 14 Tí àwọn ọmọ rẹ̀ bá pọ̀, wọ́n á fi idà pa wọ́n,+Àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ̀ ò sì ní ní oúnjẹ tó máa tó wọn.