Lúùkù 6:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ẹ sọ ọ́ di àṣà láti máa fúnni, àwọn èèyàn sì máa fún yín.+ Wọ́n máa da òṣùwọ̀n tó dáa, tí a kì mọ́lẹ̀, tí a mì pọ̀, tó sì kún àkúnwọ́sílẹ̀, sórí itan yín. Torí òṣùwọ̀n tí ẹ fi ń díwọ̀n fúnni la máa fi díwọ̀n pa dà fún yín.”
38 Ẹ sọ ọ́ di àṣà láti máa fúnni, àwọn èèyàn sì máa fún yín.+ Wọ́n máa da òṣùwọ̀n tó dáa, tí a kì mọ́lẹ̀, tí a mì pọ̀, tó sì kún àkúnwọ́sílẹ̀, sórí itan yín. Torí òṣùwọ̀n tí ẹ fi ń díwọ̀n fúnni la máa fi díwọ̀n pa dà fún yín.”