Òwe 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ahọ́n pẹ̀lẹ́* jẹ́ igi ìyè,+Àmọ́ ọ̀rọ̀ békebèke máa ń fa ìrẹ̀wẹ̀sì.*