Ìsíkíẹ́lì 18:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “‘Àmọ́ tí olódodo bá fi òdodo tó ń ṣe sílẹ̀, tó sì wá ń ṣe ohun tí kò dáa,* tó ń ṣe gbogbo ohun ìríra tí àwọn ẹni burúkú ń ṣe, ǹjẹ́ ó máa wà láàyè? Mi ò ní rántí ìkankan nínú gbogbo iṣẹ́ òdodo rẹ̀.+ Yóò kú torí ìwà àìṣòótọ́ rẹ̀ àti ẹ̀ṣẹ̀ tó dá.+ 2 Tẹsalóníkà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Èyí jẹ́ nítorí pé Ọlọ́run kà á sí òdodo láti san ìpọ́njú pa dà fún àwọn tó ń pọ́n yín lójú.+ 1 Pétérù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Tí kò bá ní rọrùn láti gba olódodo là, kí ló máa wá ṣẹlẹ̀ sí aláìṣèfẹ́ Ọlọ́run àti ẹlẹ́ṣẹ̀?”+
24 “‘Àmọ́ tí olódodo bá fi òdodo tó ń ṣe sílẹ̀, tó sì wá ń ṣe ohun tí kò dáa,* tó ń ṣe gbogbo ohun ìríra tí àwọn ẹni burúkú ń ṣe, ǹjẹ́ ó máa wà láàyè? Mi ò ní rántí ìkankan nínú gbogbo iṣẹ́ òdodo rẹ̀.+ Yóò kú torí ìwà àìṣòótọ́ rẹ̀ àti ẹ̀ṣẹ̀ tó dá.+