-
Òwe 19:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ẹlẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà,
Ẹni tí kò sì lè ṣe kó má parọ́ yóò ṣègbé.+
-
-
Ìṣe 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Bí Ananáyà ṣe gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ó ṣubú lulẹ̀, ó sì kú. Jìnnìjìnnì sì bo gbogbo àwọn tó gbọ́ nípa rẹ̀.
-