Sáàmù 91:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí o sọ pé: “Jèhófà ni ibi ààbò mi,”O ti fi Ẹni Gíga Jù Lọ ṣe ibùgbé* rẹ;+10 Àjálù kankan kò ní bá ọ,+Àjàkálẹ̀ àrùn kankan kò sì ní sún mọ́ àgọ́ rẹ.
9 Nítorí o sọ pé: “Jèhófà ni ibi ààbò mi,”O ti fi Ẹni Gíga Jù Lọ ṣe ibùgbé* rẹ;+10 Àjálù kankan kò ní bá ọ,+Àjàkálẹ̀ àrùn kankan kò sì ní sún mọ́ àgọ́ rẹ.