Òwe 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọwọ́ tó dilẹ̀ ń sọni di òtòṣì,+Àmọ́ ọwọ́ tó ń ṣiṣẹ́ kára ń sọni di ọlọ́rọ̀.+ Òwe 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọwọ́ àwọn tó ń ṣíṣẹ́ kára yóò ṣàkóso,+Àmọ́ ọwọ́ tó dilẹ̀ yóò wà fún iṣẹ́ àfipáṣe.+