Sáàmù 119:163 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 163 Mo kórìíra irọ́, mo kórìíra rẹ̀ gidigidi,+Mo nífẹ̀ẹ́ òfin rẹ.+ Òwe 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+ Éfésù 4:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí náà, ní báyìí tí ẹ ti fi ẹ̀tàn sílẹ̀, kí kálukú yín máa bá ọmọnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́,+ nítorí ẹ̀yà ara kan náà ni wá.+
13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+
25 Torí náà, ní báyìí tí ẹ ti fi ẹ̀tàn sílẹ̀, kí kálukú yín máa bá ọmọnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́,+ nítorí ẹ̀yà ara kan náà ni wá.+