-
Jeremáyà 41:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ṣùgbọ́n mẹ́wàá lára àwọn ọkùnrin náà sọ fún Íṣímáẹ́lì pé: “Má pa wá, nítorí pé a ní àlìkámà,* ọkà bálì, òróró àti oyin ní ìpamọ́ nínú oko.” Torí náà, ó dá wọn sí, kò sì pa wọ́n pẹ̀lú àwọn arákùnrin wọn.
-