Àwọn Onídàájọ́ 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ọkùnrin Éfúrémù wá sọ fún un pé: “Kí lo ṣe sí wa yìí? Kí ló dé tí o ò pè wá nígbà tí o lọ bá Mídíánì jà?”+ Wọ́n sì bínú sí i gidigidi.+
8 Àwọn ọkùnrin Éfúrémù wá sọ fún un pé: “Kí lo ṣe sí wa yìí? Kí ló dé tí o ò pè wá nígbà tí o lọ bá Mídíánì jà?”+ Wọ́n sì bínú sí i gidigidi.+