-
1 Àwọn Ọba 1:47, 48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
47 Ohun míì ni pé, àwọn ìránṣẹ́ ọba wọlé wá láti bá Ọba Dáfídì olúwa wa yọ̀, wọ́n sọ pé, ‘Kí Ọlọ́run rẹ mú kí orúkọ Sólómọ́nì gbayì ju orúkọ rẹ, kí ó sì gbé ìtẹ́ rẹ̀ ga ju ìtẹ́ rẹ!’ Ni ọba bá tẹrí ba lórí ibùsùn. 48 Ọba sì sọ pé, ‘Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó fún mi ní ẹni tó máa jókòó sórí ìtẹ́ mi, tó sì jẹ́ kó ṣojú mi lónìí!’”
-